Evang. Gideon Ayodele O. Olorun MFM (The God of MFM) mp3 download
Evang. Gideon Ayodele O. introduces another new song titled “Olorun MFM (The God of MFM)” and it’s here for quick download.
Gospel music phenomenally enormous singer Evang. Gideon Ayodele O. drops in a new track titled “Olorun MFM (The God of MFM)”.
Lyrics: Evang. Gideon Ayodele O. – Olorun MFM (The God of MFM)
Lead chorus ; Olorun MFM, Olorun alagbara.
Aiku ni o o Jesu , o ju gbogbo aye lo.
Resp (Chorus) : Olorun MFM (Oba nla),Olorun alagbara ( titobi ninu agbara ),Aiku ni o o Jesu , o ju gbogbo aye lo.
(Olorun wa) Olorun MFM,(titobi ninu ola nla )Olorun alagbara, (aiku Le ma je) aiku ni o o Jesu, o ju gbogbo aye lo
Call : o maro larada. Resp: Oba wa.
Call : O ji oku dide. Resp : Oba ni.
Call : O Sagan dolomo.
Resp: Alaini deni ibukun.
Aiku ni o Jesu, O ju gbogbo aye lo.
( Olorun wa)
Chorus : Olorun MFM……..(Titobi ninu ola o)
Call : Alagbara Lori aye.
Resp : Lori aye.
Call : Awogbaarun magbeje.
Resp : onisegun nla.
Call : Baba Alaini baba.
Resp : baba awa, oko awon opo.
Eh, Aiku ni o o Jesu, oju gbogbo aye lo.
( Olorun wa)
Chorus : Olorun MFM…… ( Oba nla nla),(alagbara lori aye),(ese o)
Olorun wa.
Chorus : Olorun MFM…….. (Titobi ninu ola nla), ( ese o)
Call : e ju gbogbo ayeeee.
Resp : O ju gbogbo aye lo.
Call : Aiku Ni o, Ai Sa ni o, Ai piyinkin, Aidibaje, Olorun OLUKOYA.
Oba to soriburuku dolori rereee. Resp : O ju gbogbo aye lo.
Call : O ju gbo gbo ayeee.
Resp : O ju gbogbo aye lo
Call : O ju gbogbo ayeee
Resp : o ju gbogbo aye lo
Call : O ju isoro wa lo.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : o ju aini wa lo.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : o ju iponju wa lo.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : Oba nla le ma je.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : Oba to n’omije mi nu.
Resp : O ju gbogbo aye lo.
Call : O so ekun mi derin.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : Titobi ninu Ola nla.
Resp: o ju gbogbo aye lo.
Call : Ti tobi ninu agbara.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
(Olorun wa)
Chorus : Olorun MFM…. (oba nla ese o),(agbe o ga)
(Olorun wa)
Chorus : Olorun MFM… ,(Olorun Olukoya) , (ajamajebi baba),(ese o)
Chorus : Olorun MFM…. (Kabi o o si),(alagbara nla),(aikule je Olorun wa o),(agbe o ga)
(Olorun wa)
Chorus : Olorun MFM…… (enikan soso ta gbojule),(alatileyin Onigbagbo),(ese o)